Ẹsira 10:41-44 BIBELI MIMỌ (BM)

41. Asareli, Ṣelemaya, ati Ṣemaraya,

42. Ṣalumu, Amaraya, ati Josẹfu.

43. Ninu ìdílé Nebo: Jeieli, Matitaya, Sabadi, Sebina, Jadai, Joẹli, ati Benaaya.

44. Gbogbo àwọn tí wọ́n fẹ́ obinrin àjèjì ni wọ́n kọ àwọn aya wọn sílẹ̀ tọmọtọmọ.

Ẹsira 10