Ẹkún Jeremaya 3:18-21 BIBELI MIMỌ (BM)

18. Nítorí náà, mo wí pé,“Ògo mi ti tán,ati gbogbo ohun tí mò ń retí lọ́dọ̀ OLUWA.”

19. Ranti ìyà ati ìbànújẹ́ mi,ati ìrora ọkàn mi!

20. Mò ń ranti nígbà gbogbo,ọkàn mi sì ń rẹ̀wẹ̀sì.

21. Ṣugbọn mo tún ń ranti nǹkankan,mo sì ní ìrètí.

Ẹkún Jeremaya 3