Àwọn Ọba Kinni 11:40-42 BIBELI MIMỌ (BM)

40. Nítorí ọ̀rọ̀ yìí, Solomoni ń wá ọ̀nà láti pa Jeroboamu, ṣugbọn Jeroboamu sá lọ sọ́dọ̀ Ṣiṣaki, ọba Ijipti, níbẹ̀ ni ó sì wà títí tí Solomoni fi kú.

41. Àwọn nǹkan yòókù tí Solomoni ṣe: gbogbo iṣẹ́ rẹ̀, ati ọgbọ́n rẹ̀, ni a kọ sinu Ìwé Ìṣe Solomoni.

42. Ogoji ọdún ni ó fi jọba lórí gbogbo Israẹli ní Jerusalẹmu.

Àwọn Ọba Kinni 11