Àwọn Ọba Keji 20:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ní àkókò kan Hesekaya ṣàìsàn tóbẹ́ẹ̀ tí ó fẹ́rẹ̀ kú. Wolii Aisaya ọmọ Amosi, wá sọ́dọ̀ rẹ̀, ó sọ fún un pé, “OLUWA ní kí o palẹ̀ ilé rẹ mọ́ nítorí pé kíkú ni o óo kú, o kò ní yè.”

2. Hesekaya bá kọjú sí ògiri, ó sì gbadura sí OLUWA, ó ní,

Àwọn Ọba Keji 20