Àwọn Ọba Keji 2:24-25 BIBELI MIMỌ (BM)

24. Nígbà tí ó yí ojú pada, tí ó rí wọn, ó ṣépè lé wọn ní orúkọ OLUWA, abo ẹranko beari meji sì jáde láti inú igbó, wọ́n fa mejilelogoji ninu àwọn ọmọ náà ya.

25. Eliṣa sì lọ sí òkè Kamẹli, láti ibẹ̀, ó lọ sí Samaria.

Àwọn Ọba Keji 2