Àwọn Ọba Keji 19:36-37 BIBELI MIMỌ (BM)

36. Senakeribu ọba Asiria bá pada sí Ninefe.

37. Ní ọjọ́ kan níbi tí ó ti ń bọ oriṣa ninu ilé Nisiroku, oriṣa rẹ̀, ni Adirameleki ati Ṣareseri, àwọn ọmọ rẹ̀ bá fi idà pa á, wọ́n sì sá lọ sí ilẹ̀ Ararati. Esaradoni ọmọ rẹ̀ bá jọba lẹ́yìn rẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 19