Sáàmù 99:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè àti Árónì wà nínú àwọn àlùfáà Rẹ̀Sámúẹ́lì wà nínú àwọn tí ó ń ké pe orúkọ Rẹ̀wọ́n képe Olúwa, ó sì dá wọn lóhùn.

Sáàmù 99

Sáàmù 99:1-9