Sáàmù 98:8-9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

8. Ẹ jẹ́ kí odo kí ó sápẹ́,ẹ jẹ́ kí òkè kí o kọrin pẹ̀lú ayọ̀;

9. Ẹ jẹ́ kí wọn kọrin níwájú OlúwaNítorí tí yóò wá ṣè dájọ́ ayébẹ́ẹ̀ ni yóò ṣe ìdájọ́ àwọn orílẹ̀-èdè nínú òdodoàti àwọn ènìyàn ní àìṣègbè pẹ̀lú.

Sáàmù 98