Sáàmù 97:4-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

4. Ìmọ́lẹ̀ Rẹ̀ tàn ó sí kárí ayéayé rí i ó sì wárìrì

5. Òkè gíga yọ́ gẹ́gẹ́ bí ìda níwájú Olúwa,níwájú Olúwa gbogbo ayé.

6. Àwọn ọ̀run ròyìn òdodo Rẹ̀, gbogbo ènìyàn sì rí ògo Rẹ̀.

7. Gbogbo àwọn tí ń sin òrìṣà ni ojú yóò ti,àwọn ti n fi ère ṣe àfẹ́rí ara wọnẸsìn ín, ẹ̀yin òrìṣà;

8. Síónì gbọ́, inú Rẹ̀ sì dùnìnú àwọn ilé Júdà sì dùnNítorí ìdájọ́ Rẹ, Olúwa

Sáàmù 97