Sáàmù 91:9-11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

9. Nítorí ìwọ fi Olúwa ṣe ààbò Rẹ,ìwọ fi Ọ̀ga Ògo ṣe ibùgbé Rẹ.

10. Búburú kan ki yóò subu lù ọ́Bẹ́ẹ̀ ni àrùnkárùn kì yóò súnmọ́ ilé Rẹ.

11. Nítorí yóò fi àṣẹ fún àwọn ańgẹ́lì nípa tìrẹláti pa ọ́ mọ ní gbogbo ọ̀nà Rẹ;

Sáàmù 91