Sáàmù 91:3-6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

3. Ní tòótọ́ òun yóò gbà mí nínúìdẹkùn àwọn pẹyẹ pẹyẹàti nínú àjàkálẹ̀-àrùn búburú.

4. Òun yóò fi ìyẹ́ Rẹ̀ bò mí,àti ni abẹ́ ìyẹ́ Rẹ̀ ni èmi yóò ti rí ààbò;òtítọ́ Rẹ̀ ni yóò ṣe ààbò àti odi mi.

5. Ìwọ kì yóò bẹ̀rù nítorí ẹ̀rù òru,tàbí fún ọfà tí ń fò ní ọ̀sán,

6. Tàbí fún àjàkálẹ̀-àrùn tí ń rìn kiri ni òkùnkùn,tàbí fún ìparun ti ń rin kirí ni ọ̀sán gangan.

Sáàmù 91