Sáàmù 87:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ó ti fi ìpilẹ̀ Rẹ̀ sọlẹ̀ sórí òkè mímọ́;

2. Olúwa fẹ́ràn ẹnu ọ̀nà Síónìju gbogbo ibùgbé Jákọ́bù lọ

3. Ohun ológo ni a sọ nípa Rẹ,ilú Ọlọ́run;

Sáàmù 87