Sáàmù 84:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ibùgbé Rẹ̀ ti lẹ́wà tó, Olúwa Olódùmarè!

2. Ọkàn mí ń fà nítòótọ́ó tilẹ̀ pòùngbẹ fún àgbàlá Olúwaàyà mi àti ara mi ń kọrin ayọ̀sí Ọlọ́run alààyè.

Sáàmù 84