Sáàmù 73:5-10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. Wọn kò ní ìpín nínú àjàgà tó ń ṣẹlẹ̀ si ènìyàn;a kò pọ́n wọn lójú nípa ẹlomíràn.

6. Ìgbéraga ni ọ̀ṣọ́ ọrùn wọn;ìwà ìpá bò wọ́n mọ́lẹ̀ bí aṣọ.

7. Láti inú ọkàn àrékérekè ni àìsòdodo ti wá;ẹ̀rí ọkàn búburú wọn kò ní òdiwọ̀n

8. Wọn ń ṣẹ̀sín, wọn sì ń sọ̀rọ̀ òdì nítiìnilára, wọn ń sọ̀rọ̀ láti ibi gíga.

9. Wọ́n ń gbé ẹ̀mí wọn lé ọ̀runahọ́n wọn gba ipò ayé.

10. Nítorí náà àwọn ènìyàn wọn yípadà sí wọnwọ́n sì mu omi ní ọ̀pọ̀lọpọ̀.

Sáàmù 73