Sáàmù 71:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Nínú Rẹ̀, Olúwa, ní mo ní ààbò;Má ṣe jẹ́ kí ojú kí ó tì mí.

2. Gbà mí kí ó sì tú mi sílẹ̀ nínú òdodo Rẹ;kọ etí Rẹ sími kí o sì gbà mí.

3. Jẹ́ àpáta ààbò mi,nibi tí èmi lè máa lọpa àṣẹ láti gbà mí,nítorí ìwọ ni àpáta àti asà mi.

Sáàmù 71