Sáàmù 66:19-20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

19. Ṣùgbọ́n Ọlọ́run gbọ́ nítòótọ́o ti gbọ́ ohun mi nínú àdúrà.

20. Ìyìn ni fún Ọlọ́runẹni tí kò kọ àdúrà mitàbí mú ìfẹ́ Rẹ̀ kúrò lọ́dọ̀ mi!

Sáàmù 66