Sáàmù 56:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ṣàánú fún mi, Ọlọ́run, nítorí àwọn ènìyàn ń fi ìgbọ́nára lépa mi;ní gbogbo ọjọ́ ni wọn ń kọjú ìjàsí mi, wọn ń ni mi lára.

2. Àwọn ọ̀ta mi ń lé mi ní gbogbo ọjọ́àwọn ènìyàn ń kọjú ìjà sí mi nínú ìgbéraga wọn.

Sáàmù 56