15. Olúwa, sí mi ní ètè mi gbogbo,àti ẹnu mi yóò sì máa kéde ìyìn Rẹ̀.
16. Nítorí ìwọ kò ní inú dídùn sí ẹbọ, tí èmi kò bá mú wá;Ìwọ kò ní inú dídùn sí ọọrẹ̀-ẹbọ sísun
17. Ẹbọ Ọlọ́run ni ìròbínújẹ́ ọkan ìròbìnújẹ́ àti ìrora àyà.
18. Ṣe rere ní dídùn inú Rẹ sí Síónì ṣe rere;tún odi Jérúsálẹ́mù mọ.