Sáàmù 49:5-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. Èéṣé ti èmi yóò bẹ̀rù nígbà tí ọjọ́ ibi déNígbà tí àwọn ènìyàn búburú àti ayan nijẹ yí mi ká,

6. Àwọn tí o gbẹ́kẹ̀lé ọrọ̀ wọntí wọn sì ń ṣe ìlérí ni ọpọlọpọ ọrọ̀ wọn

7. Kò sí ọkùnrin tí o le ra ẹ̀mí ẹnìkejì Rẹ̀padà tàbí san owó ìràpadà fúnỌlọ́run.

Sáàmù 49