Sáàmù 44:25-26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

25. Nítorí a tẹrí ọkàn wa ba sínú eruku;ara wa sì dì mọ́ erùpẹ̀ ilẹ̀.

26. Dìde kí o sì ràn wá lọ́wọ́;ràwápadà nítorí ìfẹ́ Rẹ tí ó dúró ṣinṣin.

Sáàmù 44