Sáàmù 28:8-9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

8. Olúwa ni agbára àwọn ènìyàn Rẹ̀òun ni odi ìgbàlà àwọn àyànfẹ́ẹ Rẹ̀.

9. Ìwọ gba àwọn ènìyàn Rẹ là, kí o sì bùkún àwọn ajogún Rẹ;di olùsọ́ àgùntàn wọn, kí o sì gbé wọn lékè títí ayérayé.

Sáàmù 28