Sáàmù 28:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ìwọ Olúwa, mo képe àpáta mi;Má ṣe kọ eti dídi sí mi.Tí ìwọ bá dákẹ́ sí mi,èmí yóò dàbí àwọn tí ó lọ sí ọ̀gbun.

2. Gbọ́ ohùn ẹ̀bẹ̀ mi fún àánú,bí mo ṣe ń ké pé ọ́ fún ìràn lọ́wọ́,bí mo ṣe gbé àwọn ọwọ́ mi sókèsí ibi mímọ́ Rẹ jùlọ.

3. Má ṣe fà mí lọ pẹ̀lú ènìyàn búburú àti,pẹ̀lú àwọn oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀,tí ń sọ̀rọ̀ àlàáfíà sí aládùúgbò wọnṣùgbọ́n tí ìwà ìkà ń bẹ nínú wọn.

Sáàmù 28