Sáàmù 18:49-50 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

49. Títí láéláé èmi yóò máa yìn ọ́ láàrin àwọn orílẹ̀ èdè, ìwọ Olúwa;Èmi yóò sì máa kọ orin ìyìn sí orúkọ Rẹ.

50. Ó fún Ọba Rẹ̀ ni ìṣẹ́gun ńlá;ó fi ìkáànú àìṣẹ̀tàn fún ẹni-àmì-òróró Rẹ̀,fún Dáfídì àti ìran Rẹ̀ títí láé.

Sáàmù 18