Sáàmù 148:12-14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

12. Ọ̀dọ́mọkùnrin àti ọ̀dọ́mọbìnrinàwọn arúgbó àti àwọn ọmọdé.

13. Ẹ jẹ́ kí wọn kí ó yin orúkọ Olúwanítorí orúkọ Rẹ̀ nìkan ni ó ní ọláògo Rẹ̀ kọjá ayé àti ọ̀run

14. Ó sì gbé ìwo kan sókè fún àwọn ènìyàn Rẹ̀,ìyìn fún gbogbo ènìyàn mímọ́ Rẹ̀ àní fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì,àwọn ènìyàn tí ó súnmọ́ ọ̀dọ̀ Rẹ̀.Ẹ fi ìyìn fún Olúwa.

Sáàmù 148