Sáàmù 146:3-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

3. Ẹ má ṣe ní ìgbẹkẹ̀lé nínú àwọn ọmọ aládé,àní, ọmọ ènìyàn,lọ́wọ́ ẹni tí kò sí ìrànlọ́wọ́.

4. Ẹ̀mí Rẹ jáde lọ, ó padà sí erùpẹ̀ Rẹ̀:Ní ọjọ́ náà gan, èrò wọn yóò di òfo:

5. Ìbùkún ni fún ẹni tíỌlọ́run Jákọ́bù ń ṣe ìrànlọ́wọ́ Rẹ̀tí ìrètí Rẹ̀ wà nínú Olúwa Ọlọ́run Rẹ̀,

Sáàmù 146