Sáàmù 146:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ fi ìyìn fún Olúwa,fi ìyìn fún Olúwa, ìwọ ọkàn mi

2. Èmi yóò yin Olúwa ní gbogbo ayé mièmi yóò kọrin ìyìn sí Ọlọ́run,níwọ̀n ìgbà tí mo bá wà láàyè.

Sáàmù 146