Sáàmù 144:14-15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

14. Àwọn màlúù wa yóò ru ẹrù wúwokí ó má sí ìkọlù,kí ó má sí ìkólọ sí ìgbèkùn,kí ó má síi igbe ìpọ́njú ní ìgboro wa.

15. Ìbùkún ni fún àwọn ènìyàn náàtí ó wà ní irú ipò bẹ́ẹ̀, Ayọ̀ ni fún àwọntí ẹni ti Ọlọ́run Olúwa ń ṣe.

Sáàmù 144