Sáàmù 144:10-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

10. Sí ẹni tí ó fún àwọn ọba ní ìsẹ́gun,ẹni tí ó gba Dáfídì ìránṣẹ́ Rẹ̀lọ́wọ́ pípanirun.

11. Gbàmí kí ó sì yọ mí nínú ewukúrò lọ́wọ́ àwọn ọmọ àjèjìtí ẹnu wọn kún fún èké,tí ọwọ́ ọ̀tún wọn jẹ́ ọwọ́ ọ̀tún èké.

12. Kí àwọn ọmọkùnrin wa kí ó dàbí igigbígbin tí ó dàgbà ni ìgba èwe wọn,àti ọmọbìnrin wa yóò dàbí òpó ilétí a ṣe ọ̀nà sí bí àfarawé ààfin.

Sáàmù 144