Sáàmù 136:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ fi ọpẹ́ fún Olúwa nítorí tí ó ṣeun;nítorí tí àánú Rẹ̀ dúró láéláé.

2. Ẹ fi ọpẹ́ fún Ọlọ́run àwọn ọlọ́run:nítorí tí àánú Rẹ̀ dúró láéláé.

3. Ẹ fi ọpẹ́ fún Olúwa àwọn Olúwa,nítorí tí àánú Rẹ̀ dúró láéláé.

Sáàmù 136