Sáàmù 135:10-14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

10. Ẹni tí ó kọlu àwọn orílẹ̀ èdè púpọ̀,tí ó sì pa àwọn alágbára ọba.

11. Síónì, ọba àwọn ará Ámorì, àti Ógù,ọba Báṣánì, àti gbogbo ìjọba Kénánì:

12. Ó sì fi ilẹ̀ wọn fúnni ní ìní,ìní fún Ísírẹ́lì, ènìyàn Rẹ̀.

13. Olúwa orúkọ Rẹ dúró láéláé;ìrántí Rẹ Olúwa, láti ìran-díran.

14. Nítorí tí Olúwa yóò ṣe ìdájọ́ àwọn ènìyàn Rẹ̀,yóò sì ṣe ìyọ́nú sí àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ Rẹ̀.

Sáàmù 135