Sáàmù 129:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ìgbà púpọ̀ ni wọ́n ti pọ́n mi lójúláti ìgbà èwe mi wá ni kíÍsírẹ́lì kí ó wí nísinsinyí

2. Ìgbà púpọ̀ ni wọ́n ti pọ́n mi lójúláti ìgbà èwe mi wá;ṣíbẹ̀ wọn kò tíì borí mi.

Sáàmù 129