Sáàmù 119:147-151 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

147. Èmi dìde ṣáájú àfẹ̀mọ́júmọ́ èmi ké fún ìràn lọ́wọ́;èmi ti mú ìrètí mi sínú ọ̀rọ̀ Rẹ.

148. Ojú mi ṣááju ìsọ́ òru,nítorí kí èmi lè ṣe àṣàrò nínú ọ̀rọ̀ r.

149. Gbọ́ ohùn mi ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú ìfẹ́ Rẹ:pa ayé mí mọ́, Olúwa, gẹ́gẹ́ bí òfin Rẹ.

150. Àwọn tí ń gbìmọ̀ ìlànà búburú wà ní tòòsí,ṣùgbọ́n wọ́n jìnnà sí òfin Rẹ.

151. Ṣíbẹ̀ ìwọ wà ní tòsí, Olúwa,àti gbogbo àsẹ Rẹ jẹ́ òtítọ́.

Sáàmù 119