Sáàmù 116:10-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

10. Èmi gbàgbọ́; nítorí náà mo wí pé,“èmi rí ìpọ́njú púpọ̀”.

11. Àti nínú ìdààmú mi mo wí pé“Èké ni gbogbo ènìyàn”.

12. Kí ni èmi yóò san fún Olúwanítorí gbogbo rere Rẹ̀ sí mí?

Sáàmù 116