Sáàmù 115:3-6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

3. Ṣùgbọ́n Ọlọ́run wa wà lọ́run:tí ó ń ṣe èyí tí ó wù ú.

4. Òrìṣà fàdákà àti wúrà,iṣẹ́ ọwọ́ ènìyàn

5. Wọn ní ẹnu, ṣùgbọ́n wọn kò lè sọ̀rọ̀,wọn ní ojú, ṣùgbọ́n wọn kò fi ríran.

6. Wọ́n ní etí, ṣùgbọ́n wọn kò gbọ́ràn:wọ́n ní imú, ṣùgbọ́n wọ́n kò fi gbóòórùn

Sáàmù 115