Sáàmù 113:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ máa yin Olúwa, yìn ín ẹ̀yin ìránṣẹ́ Olúwa,ẹ yin orúkọ Olúwa.

2. Fi ìbùkún fún orúkọ Olúwa látiìsinsin yìí lọ àti títí láéláé.

Sáàmù 113