Sáàmù 112:2-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

2. Iru ọmọ Rẹ̀ yóò jẹ́ alágbára ní ayé:ìran àwọn olóòótọ́ ni a ó bùkún fún

3. Ọlá àti ọrọ̀ yóò wà nínú ilé Rẹ̀:òdodo Rẹ̀ sì dúró láé.

4. Fún olóòótọ́ ni ìmọ́lẹ̀ yóò tàn fún ni òkùnkùn:olóore ọ̀fẹ́ àti aláàánú àti òdodo.

Sáàmù 112