Sáàmù 108:6-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. Gbà wá kí ó sì ràn wá lọ́wọ́, pẹ̀lúọwọ́ ọ̀tún Rẹ, se igbala,ki o si da mi lóhùn

7. Ọlọ́run ti sọ̀rọ̀ níbi mímọ́“Ní ìsẹ́gun ní èmi ó ké Sékémùèmi yóò sì wọ́n ibi gíga Sukobù

8. Gílíádì ni tèmi, Mánásè ni tèmiÉfuraimù ní ìbòrí miJúdà ní olófin mi

Sáàmù 108