Róòmù 9:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ̀yin ọmọ Ísírẹ́lì, ìbátan mi nípa ti ara, ó wù mí púpọ̀ láti rí i pé ẹ gba Kírísítì gbọ́.

2. Ọkàn mi gbọgbẹ́, mo sì ń joró lọ́sán àti lóru nítorí yín.

Róòmù 9