Róòmù 15:31-33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

31. Kí a lè kó mi yọ kúrò lọ́wọ́ àwọn aláìgbàgbọ́ ní Jùdíà àti kí isẹ́ ìránsẹ́ tí mo ní sí Jérúsálẹ́mù le jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà lọ́dọ̀ àwọn ènìyàn mímọ́ níbẹ̀.

32. Nítorí náà, nípa ìfẹ́ Ọlọ́run kí èmi le fi ayọ̀ tọ̀ yín wa, kí pọ̀ pẹ̀lú yín ní ìtura.

33. Kí Ọlọ́run àlàáfíà wà pẹ̀lú gbogbo yín. Àmín.

Róòmù 15