Òwe 9:15-17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

15. ó ń pe àwọn tí ó ń kọjá lọ,tí wọn ń lọ tààrà ní ọ̀nà wọn.

16. “Jẹ́ kí gbogbo ẹni tí ó jẹ́ aláìlóye súnmọ́ bí!”Ni ó wí fún ẹni tí òye kù díẹ̀ ká à tó fún.

17. “Omi tí a jí mu dùnoúnjẹ tí a jẹ ní ìkọ̀kọ̀ a máa ládùn!”

Òwe 9