Òwe 4:25-27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

25. Jẹ́ kí ojú ù rẹ máa wo iwájú,jẹ́ kí ìwo ojú ù rẹ máa wo ọ̀kánkán iwájú rẹ sáá.

26. Kíyèsí ìrìn ẹṣẹ̀ rẹsì rìn ní àwọn ọ̀nà tí ó dára nìkan

27. má ṣe yà sọ́tùn-ún tàbí ṣósìpa ẹṣẹ̀ rẹ mọ́ kúrò nínú ibi.

Òwe 4