Òwe 29:26-27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

26. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ń wá ojúrere alákòóṣo,ṣùgbọ́n láti ọdọ Olúwa ni ènìyàn tí ń gba ìdájọ́ òdodo.

27. Olódodo kórìíra àwọn aláìsòótọ́:ènìyàn búburú kórìíra olódodo.

Òwe 29