Òwe 28:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ènìyàn búburú ń sá bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹnìkan kò lé eṣùgbọ́n olódodo láyà bí i kìnnìún.

2. Nígbà tí orílẹ̀ èdè bá ní orí kunkun, àwọn ọba rẹ̀ a máa pọ̀ṣùgbọ́n olóye àti onímọ̀ a máa pa òfin mọ́

Òwe 28