Òwe 13:19-21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

19. Ìfẹ́ tí a múṣẹ dùnmọ́ ọkànṣùgbọ́n ìríra ni fún aṣiwèrè láti kúrò nínú ibi.

20. Ẹni tí ó ń bá ọlọ́gbọ́n rìn yóò gbọ́nṣùgbọ́n ẹni tí ń bá aláìgbọ́n kẹ́gbẹ́ ń pa ara rẹ̀ lára.

21. Òsì a máa ta ẹlẹ́ṣẹ̀,ṣùgbọ́n ọrọ̀ ni èrè fún olódodo.

Òwe 13