Òwe 1:28-30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

28. “Nígbà náà ni wọn yóò ké pè mí ṣùgbọ́n, èmi kò ní dáhùn;wọn yóò farabalẹ̀ wá mi ṣùgbọ́n wọn kì yóò rí mi.

29. Níwọ̀n bí wọ́n ti kórìíra ìmọ̀tí wọ́n sì kọ̀ láti bẹ̀rù Olúwa.

30. Níwọ̀n bí wọn kò ti gbà ìmọ̀ràn mití wọ́n sì kẹ́gàn ìmọ̀ràn mi,

Òwe 1