Oníwàásù 12:13-14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

13. Níṣinsìn yìí,òpin gbogbo ọ̀rọ̀ tí a gbọ́ ni pé:Bẹ̀rù Ọlọ́run, kí o sì pa òfin rẹ̀ mọ́,nítorí èyí ni ojúṣe gbogbo ènìyàn.

14. Nítorí Ọlọ́run yóò ṣe ìdájọ́ olúkúlùkù iṣẹ́àti ohun ìkọ̀kọ̀,kì bá à ṣe rere kì bá à ṣe búburú.

Oníwàásù 12