Nọ́ḿbà 34:19-21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

19. Èyí ni orúkọ wọn:Kálẹ́bù ọmọ Jéfúnè,láti ẹ̀yà Júdà;

20. Ṣémúélì ọmọ Ámíhúdì,láti ẹ̀yà Ṣíméónì;

21. Élídádì ọmọ Kísílónì,láti ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì;

Nọ́ḿbà 34