Nọ́ḿbà 31:42-44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

42. Ààbọ̀ tí ó jẹ́ ti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, tí Mósè yà sọ́tọ̀ kúrò lára àwọn ọkùnrin tí ó ja ogun.

43. (Ààbọ̀ tí àwọn ará ìlú sì jẹ́ ẹgbàá méjìdínláàdọ́sàn-án ó lé ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀jọ (337,500) àgùntàn,

44. pẹ̀lú ẹgbàá méjìdínlógún (36,000) màlúù

Nọ́ḿbà 31