Nehemáyà 11:32-36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

32. Ní Ánátótì, Nóbù àti Ánáníyà,

33. Ní Háṣórì Rámà àti Gítaímù,

34. Ní Hádídì, Ṣébóimù àti Nébálátì,

35. Ní Lódì àti Ónò, àti ní àfonífojì àwọn gbẹ́nàgbẹ́nà.

36. Nínú ìpín àwọn ọmọ Léfì ni Júdà tẹ̀dó sí Bẹ́ńjámínì.

Nehemáyà 11