Mátíù 3:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsin yìí, a ti fi àáké lè gbòǹgbò igi, àti pé gbogbo igi tí kò bá so èso rere ni a óò gé lulẹ̀ ti a ó sì jù wọn sínú iná.

Mátíù 3

Mátíù 3:3-15